For Imminent: An Article on Indigenous Nigerian Languages Online

 
 

“The online use of Nigerian indigenous languages by Nigerians in Nigeria, Nigerians in the diaspora, and even non-Nigerians who speak the language, has become a medium of connection, a unifying force that drives pride of culture. In a sense, it is also a potential tool for minimising exclusion. Nigerian social media can be elitist in that most of the content is in English, excluding those who don’t speak the language, which is usually those who mostly live in non-urban areas of Nigeria or have not received education in English. More content in indigenous languages offers inclusion to a wider group of people.”

Read the rest HERE.

“Ìlò àwọn èdè abínibí Naijiria lori intanẹẹti nípasẹ̀ àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria ni Naijiria, awọn orílẹ̀-èdè Naijiria ní òkè-òkun, ati pàápàá awọn tí kií ṣe ọmọ Naijiria tí wọ́n ń sọ èdè naa, ti jẹ́ kí ó di ohun èlò ìsopọ̀, ohun èlò ìsọ̀kan alagbara tó ń mú ìwúrí bá àsà. Ní ọ̀nà kan, ó tún seése kí ó jẹ́ ohun èlò lati mú àdínkù bá ìyàsọ́tọ̀. Ìtàkurọ̀sọ àwùjọ (social media) ti Naijiria wà fún awọn tí ó kàwé nitori pe èdè Gẹ̀ẹ́sì ní wọ́n ṣábà maa n fi kọọ́, èyí kò kan àwọn tí kìí sọ èdè naa, ìyẹn àwọn tí wọ́n ń gbé ní àwọn ìgbèríko Naijiria tàbí àwọn tí wọn kò kọ́ ẹ̀kọ́ ní èdè Gẹ̀ẹ́sì. Ọ̀pọ̀ àkọsílẹ̀ tí a fi ọgbọ́n inù gbékalẹ̀ tí a kọ ní èdè abínibi maa ń tàn dé ọ̀pọ̀ ẹgbẹ́ awọn eniyan.

Read the rest HERE.